Fárótìkà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fárótìkà
Ifá did not stand with the wicked.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-à-ró-tì-ìkà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusà - did not
ró - stand (dúró)
tì - with
ìkà - a cruel/evil thing/person
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO