Fámúrewá

Sísọ síta



Ìtumọọ Fámúrewá

Ifá brought goodness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-mú-ire-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination
mú...wá - bring
ire - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Múrewá