Sísọ síta
Ifá is whom I stand with.
ifá-mo-dúró-tì
Ó pọ̀ ní: EKITI ONDO
Fámurótì
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.