Fálúàdé
Sísọ síta
Ìtumọọ Fálúàdé
Ifá brought celebration.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-ní-ùà-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusní - have
ùà - the society, a gathering, celebration
dé - arrive, return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI