Fákúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fákúnlé

Ifá has taken over [filled] the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination
kún - fill, add to
ilé - house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ifákúnlé