Fájuyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Fájuyì
Ifá did not permit honour to waste.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(i)fá-(à)-jẹ-(kí)-uyì-(gbé)
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/priesthood/corpusà - does not
jẹ́ - let
uyì - honour, value
gbé - waste
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Lt. Colonel Adékúnlé Fájuyì (26 June 1926 – 29 July 1966): former military administrator of Western Nigeria
assassinated alongside his Commander
Major General Aguiyi Ironsi in a counter coup in Ibadan.