Fájíngbésì

Sísọ síta



Ìtumọọ Fájíngbésì

Ifá lets me get a response.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-jẹ́-(kí)-n-gbọ́-èsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination
jẹ́ - let
n - me
gbọ́ - listen, hear
èsì - response


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Fájẹ́ngbésì

Fájẹ́mgbésì