Fágbohùn

Sísọ síta



Ìtumọọ Fágbohùn

Ifá received (our) voice.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-gba-ohùn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá (oracle)
gbà - take, collect, receive
ohùn - voice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Fágboùn