Fágbàmígbé
Sísọ síta
Ìtumọọ Fágbàmígbé
Ifá did not forget me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-ò-gbà...gbé-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
(i)fá - ifá divination, corpus, priesthoodò - did not
gbà...gbé - forget
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO