Fáfiyèbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Fáfiyèbí

Ifá birthed this with wisdom.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-fi-iyè-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ifá - Ifá divination, corpus, priesthood
fi - use
iyè - wisdom, depth
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ILESHA



Irúurú

Ifáfiyèbí

Fiyèbí