Fádiwúrà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fádiwúrà
Ifá has become (as precious as) gold.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-di-wúrà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá (oracle), divination, priesthood, Ọ̀rúnmìlàdi - become
wúrà - gold
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL