Fádìran

Sísọ síta



Ìtumọọ Fádìran

Ifá becomes hereditary.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-di-ìran



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - ọ̀rúnmìlà, Yorùbá god of knowledge, intellect, wisdom
di - to become, to pack (as in a luggage)
ìran - vision, ancestry


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Dìran