Fábíọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Fábíọ́lá
Ifá gave birth to prestige.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-bí-(sí)-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, corpus, priesthoodbí - give birth to
(sí) - into
ọlá - prestige, wealth, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL