Fọpẹ́fólúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Fọpẹ́fólúwa

Give thanks to God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ọpẹ́-fún-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - give, grant
ọpẹ́ - thanksgiving
fún - for, to
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Afọpẹ́fólúwa

Fọpẹ́

Fọpẹ́fólú