Fọláwọlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fọláwọlé

Enter with wealth/nobility/notability.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ọlá-wọ-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ọlá - wealth, success, nobility, notability
wọ̀ - enter
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO
GENERAL



Irúurú

Fọlá

Wọlé