Fọlárinlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fọlárinlé

Brought wealth home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ọlá-rin-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ọlá - wealth/success/nobility
rìn - walk, affect
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO