Fọláṣìkẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Fọláṣìkẹ́mi

Cherish me with wealth/success/nobility.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ọlá-ṣe-ìkẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ọlá - wealth, success
ṣe - make
ìkẹ́ - care for
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL