Fẹ̀sọ̀mádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fẹ̀sọ̀mádé

Gently possess the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ẹ̀sọ̀-mú-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ẹ̀sọ̀ - gentility, cunning
mú - pick, take, possess
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Mádé