Fẹ̀sọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Fẹ̀sọ̀

With ease.



Àwọn àlàyé mìíràn

See longer names like Fẹ̀sọ̀bí, Olúfẹ̀sọ̀bí, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ẹ̀sọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - used
ẹ̀sọ̀ - gentility, cunning, calm


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fẹ̀sọ̀bí

Olúfẹ̀sọ̀bí

Adéfẹ̀sọ̀

Olúfẹ̀sọ̀

Adéfẹ̀sọ̀bí

Ògúnfẹ̀sọ̀