Fúnṣọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Fúnṣọ́

Given (by God) to cherish/protect, etc. A shortening of names like Olúfúnṣọ́, Adéfúnṣọ́, Oyèfúnṣọ́, etc.



Àwọn àlàyé mìíràn

Also written as Fúnshọ́



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fún-n-ṣọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fún - to give to
n - me (mi)
ṣọ́ - watch over, protect


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fúnshọ́