Fùsìká
Sísọ síta
Ìtumọọ Fùsìká
See: Ọláfùsìká, Ògúnfùsìká, etc
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
fù-ùṣì-ká
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
fù - showed/exhibited (as related to behaviour). Also: wùùṣì - prominence
ká - around, about
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO