Fẹ̀sọ̀lògbà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fẹ̀sọ̀lògbà
Be patient/calm when living (literally "when spending time").
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
fi-ẹ̀sọ̀-lò-ìgbà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
fi - useẹ̀sọ̀ - gentility, cunning, calm
lò - use, make us of, utilize.
ìgbà - time, season
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL