Fẹ̀sọ̀jayé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fẹ̀sọ̀jayé

Use ease to enjoy life.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ẹ̀sọ̀-jayé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - used
ẹ̀sọ̀ - gentility, cunning, calm
jayé - enjoy life


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL