Fáyùnsìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Fáyùnsìn

It is sweet to worship Ifá.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-yùn-sìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
yùn - to be sweet (dùn)
sìn - worship, serve


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifáyùnsìn

Fádùnsìn

Fádùsìn