Fáwòmójú

Sísọ síta



Ìtumọọ Fáwòmójú

Ifá stared at me in the face.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-wò-mọ́-ojú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
- look, stare at
mọ́ - with
ojú - face


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ifáwòmójú

Wòmójú