Fátúsìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Fátúsìn
Ifá is worth worshipping.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Ifátúsìn.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-tún-sín
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá corpus, priesthood, divinationtún - suffice for (tó)
sín - worship
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
GENERAL