Sísọ síta
Ifá repaired the throne.
Ifá-tún-ìgà-ṣe
Ó pọ̀ ní: IJEBU
Ifátúngàṣe
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.