Fátúmikẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Fátúmikẹ́

Ifá has cherished me again; Ifá has provided care again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-tún-mi-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá (oracle)
tún - again
mi - me
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Ifátúmikẹ́

Túmikẹ́

Túnmikẹ́