Fátúkàsí
Sísọ síta
Ìtumọọ Fátúkàsí
Ifá is worth giving regard/respect to.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-tú-ka...sí-èyí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ọ̀rúnmìlà, god of knowledge, intellect, wisdomtú - is worth (tó)
ka...sí - to give value to, to count as important
èyí - this
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA