Fátórègún
Sísọ síta
Ìtumọọ Fátórègún
Ifá is worthy of making a request for previous favor granted.
Àwọn àlàyé mìíràn
See Fátìrègún, Fánírègún, Fásìrègún
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-tó-règún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpustó - suffice for
règún - to make a request for previous favor granted; to recount or repeatedly mention to someone that you granted a favor for in the past
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN