Fátìmẹ́hìntì

Sísọ síta



Ìtumọọ Fátìmẹ́hìntì

A variant of Fátìmẹ́yìntì, Ifá is still able to be relied on.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-à-tì-mú...ẹ̀yìn...tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
à - did not
- support
mú...ẹ̀yìn...tì - retire


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Ifátìméyìntì

Ifátìmẹ́hìntì

Fátìmẹ́yìntì

Fátùméyìntì

Fátìméyìn

Fátìmẹ́hìn