Fásùnlúà

Sísọ síta



Ìtumọọ Fásùnlúà

1. Ifá rests upon good character. 2. Ifá rests upon the society.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-sùn-lé-ùà, ifá-sùn-lé-ùwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination/priesthood/corpus
sùn - sleep, rest, rely
- on
ùà - the society, a gathering, celebration
ùwà - character (ìwà)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifásùnlúà

Fásùnlúwà