Fárínú

Sísọ síta



Ìtumọọ Fárínú

Ifá sees what is inside (my heart/mind).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-rí-inú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpus
- see, find
inú - stomach, inside, heart


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifárínú

Rínú