Fáparúsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Fáparúsì

Ifá has completed our notability.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-parí-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, worship, brotherhood, Ọ̀rúnmìlà
parí - complete
ùsì - fame, reputation


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifáparúsì