Fámorítiyé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fámorítiyé

Ifá's message has become clear.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-mo-rí-ti-yé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus, brotherhood
mo - I
- see, find
ti - has
- understand/be understood


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Ifámorítiyé Òpókìtì

  • Alárá ti Ìlárá-Mọ̀kín



Irúurú

Ifámorítiyé