Fámiwọlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fámiwọlé

My Ifá has entered the house.



Àwọn àlàyé mìíràn

Can also be interpreted as "the result of my Ifá divination has entered the house."



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-mi-wọ-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, priesthood
mi - me
wọ - enter
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifámiwọlé

Fáwọlé