Fámiládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fámiládé

My Ifá owns a crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-mi-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, brotherhood
mi - me
- have
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ifámiládé