Fámẹ̀yẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Fámẹ̀yẹ
Ifá is familiar with honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-mọ̀-ẹ̀yẹ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusmọ̀ - know, be familiar with
ẹ̀yẹ - honour, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI