Fámúyìwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Fámúyìwá

Ifá has brought this (goodness).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-mú-èyí-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination
mú...wá - bring
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ifámúyìwá

Múyìwá