Fámúṣẹ̀ṣọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Fámúṣẹ̀ṣọ́
1. Ifá used this child as a guardian. 2. Ifá used this child as beauty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-mú-ṣe-ẹ̀ṣọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusmú - to use; to hold (onto)
ṣe - make
ẹ̀ṣọ́ - guard, protector, warrior (ọ̀ṣọ́), adornment (ẹ̀ṣọ́)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE