Fámóríjì
Sísọ síta
Ìtumọọ Fámóríjì
Ifá forgave/forgives.
Àwọn àlàyé mìíràn
See Fáforíjì, Fáforíjìn.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-mú-orí-jì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/priesthood/corpusmú - to use; to hold (onto); to make
orí - head, body
jì - gift, to entrust (jìn)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI