Fálọ̀yọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Fálọ̀yọ̀

Ifá is joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-ni-ọ̀yọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
ni - is
ọ̀yọ̀ - excitement, joy (ayọ̀)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Ifálọ̀yọ̀