Fákúàjọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Fákúàjọ

Ifá has brought a gathering together (for celebration).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-kó-ùà-jọ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, priesthood
- gather
ùà - a gathering, a group of people, a celebration
jọ - together, jointly


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
EKITI



Irúurú

Fákụ́wàjọ

Fákúwàjọ

Ịfákụ́àdé

Fákụ́àdé

Ọlọ́finkụ́àdé

Ọ̀ṣàákụ́àdé