Fákọ́lọgbọ́n

Sísọ síta



Ìtumọọ Fákọ́lọgbọ́n

Ifá has brought the wise one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-kó-o-ni-ọgbọ́n



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, brotherhood
- to bring
o - one who
ni - is
ọgbọ́n - wisdom


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ifákọ́lọgbọ́n