Fákọ́lájọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Fákọ́lájọ
Ifá has gathered honor together.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-kó-ọlá-jọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpuskó - gather
ọlá - wealth/nobility/success
jọ - together
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI