Fájẹ́midàgbà

Sísọ síta



Ìtumọọ Fájẹ́midàgbà

1. Ifá allowed me to grow old. 2. Ifá, let me grow old.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-jẹ́-mi-di-àgbà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
di - become
àgbà - elder


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI