Fájíládé
Sísọ síta
Ìtumọọ Fájíládé
Ifá has woken up in royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-jí-ní-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, corpus, brotherhoodjí - wake up
ní - have, own; into
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI