Fágbọrọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Fágbọrọ̀
Ifá has received riches.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-gba-ọrọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpusgba - receive, take/take over, accept
ọrọ̀ - wealth, riches
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI