Fágbọ́lágún

Sísọ síta



Ìtumọọ Fágbọ́lágún

Ifá has aligned honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-gbé-ọlá-gún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, worship, brotherhood, Ọ̀rúnmìlà
gbé - carry
ọlá - success, nobility, wealth
gún - set, to align, to be good.


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
EKITI



Irúurú

Ifágbọ́lágún