Fágbọ̀nmírè

Sísọ síta



Ìtumọọ Fágbọ̀nmírè

Ifá did not abandon me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-à-gbọ̀n...rè-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, brotherhood
à - did not
gbọ̀n...rè - ignore, deprive
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO



Irúurú

Ifágbọ̀nmírè

Gbọ̀nmírè